Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 1, 2010
Ṣé Ọlọ́run Ti Pa Wá Tì Ni?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
13 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
14 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Dúró Lórí Ohun Tó O Gbà Gbọ́!
16 Ohun Tá A Rí Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Bí A Ṣe Lè Tẹ̀ Lé Kristi
18 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bá A Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Kan Di Ẹni Tó Dáńgájíá
26 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
30 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Nígbà Tí ‘Ọkàn Tí Ó Ní Ìròbìnújẹ́ Tí Ó sì Wó Palẹ̀’ Bá Tọrọ Ìdáríjì
31 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
8 Kí Làwọn Tí Ọkọ Tàbí Aya Wọn Kú Nílò?—Báwo Lo Ṣe Lè Ràn Wọ́n Lọ́wọ́?
21 Jèhófà, Orúkọ Ọlọ́run, Wà Nínú Tẹ́ńpìlì Íjíbítì Kan
23 A Wàásù “Ìhìn Rere” ní Àwọn Erékùṣù Jíjìnnà Réré Ní Àríwá Ọsirélíà