Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 15, 2010
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
August 30–September 5
Ohun Tí Ọjọ́ Jèhófà Máa Ṣí Payá
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 133, 40
September 6-12
“Irú Ènìyàn Wo Ni Ó Yẹ Kí Ẹ Jẹ́!”
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 61, 29
September 13-19
Máa Kó Ipa Tó Jọjú Nínú Ìkórè Tẹ̀mí
OJÚ ÌWÉ 16
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 103, 102
September 20-26
“Ẹ̀mí Ń Wá Inú . . . Àwọn Ohun Ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run”
OJÚ ÌWÉ 20
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 71, 117
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11
Nínú lẹ́tà kejì tí àpọ́sítélì Pétérù kọ, ó fi hàn pé ọ̀rọ̀ àwọn Kristẹni tó ń gbé ní àkókò òpin jẹ òun lógún gan-an. Àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí máa ràn wá lọ́wọ́ láti fi ọjọ́ Jèhófà sọ́kàn pẹ́kípẹ́kí. A máa ṣàgbéyẹ̀wò àwọn ohun tá a gbọ́dọ̀ máa yẹra fún àtàwọn ohun tá a gbọ́dọ̀ máa ṣe ká lè wà ní ìmúrasílẹ̀ de ọjọ́ ńlá Jèhófà.
ÀPILẸKỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 16 sí 20
Àkókò tí ìkórè ńlá tẹ̀mí ń lọ ní pẹrẹu la wà yìí. Àwọn ànímọ́ wo la nílò ká lè máa kópa tó jọjú nínú iṣẹ́ ìwàásù? Báwo la ṣe lè ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe nígbà tí nǹkan ò bá rọgbọ? Àpilẹ̀kọ yìí máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí.
ÀPILẸKỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24
Àpilẹ̀kọ yìí ṣàgbéyẹ̀wò ohun tí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa lè ṣe ká lè jàǹfààní kíkún nínú ipa tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń kó láti mú ká lóye Ọ̀rọ̀ rẹ̀.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
“Má Fòyà. Èmi Fúnra Mi Yóò Ràn Ọ́ Lọ́wọ́” 12
Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Láti Nífẹ̀ẹ́ sí Ìwé Kíkà àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ 25
“Máa Bá A Lọ ní Fífi Ara Rẹ . . . fún Kíkọ́ni” 29