Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 15, 2010
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
September 27–October 3
Bí Jésù Ṣe Gbé Òdodo Ọlọ́run Lárugẹ
OJÚ ÌWÉ 8
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 46, 133
October 4-10
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 62, 99
October 11-17
Jẹ́ Kí “Òfin Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́” Máa Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ahọ́n Rẹ
OJÚ ÌWÉ 21
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 77, 79
October 18-24
Ta Ló Lè Dá Àwọn Tó Ń Kígbe fún Ìrànlọ́wọ́ Nídè?
OJÚ ÌWÉ 28
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 68, 23
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 8 sí 16
ẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Sátánì ṣe pe Ọlọ́run níjà. Ṣàgbéyẹ̀wò bí Jésù ṣe gbé ẹ̀tọ́ Jèhófà gẹ́gẹ́ bí ọba aláṣẹ ayé àtọ̀run lárugẹ. Ronú lórí bí ẹbọ ìràpadà Jésù ṣe níye lórí tó, kó o sì mọ bó ṣe lè gbà ẹ́ là. Àwọn kókó yìí la jíròrò nínú àwọn àpilẹ̀kọ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 21 sí 25
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tí inú-rere-onífẹ̀ẹ́ jẹ́ àti bí ó ṣe lè nípa lórí bí a ṣe ń lo ahọ́n wa. Tún ronú lórí àwọn ọ̀nà tá a lè máa gbà fi ànímọ́ Ọlọ́run yìí hàn nínú ọ̀rọ̀ tí à ń sọ lójoojúmọ́.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 28 sí 32
Ìwé Sáàmù 72, sọ bí nǹkan ṣe máa rí nígbà Ìṣàkóso Ẹgbẹ̀rún Ọdún, Jésù Kristi, Ọmọ Ọlọ́run. Wàá rí ìtùnú àti ìṣírí gbà bó o ti ń kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí tó o sì ń ṣàṣàrò lórí bí Jèhófà Ọlọ́run ṣe máa lo Sólómọ́nì Títóbi Jù láti dá àwọn èèyàn tó ń kígbe fún ìrànlọ́wọ́ nídè.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Má Ṣe Jẹ́ Kí Èrò Àwọn Èèyàn Máa Darí Rẹ 3
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé 6
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Máa Dé Lásìkò? 25