Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 15, 2010
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
December 27, 2010–January 2, 2011
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Darí Yín
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 37, 57
January 3-9, 2011
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Má Ṣe Fàyè Gba Ẹ̀mí Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 24, 52
January 10-16, 2011
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Kí Lẹ Máa Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe?
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 95, 89
January 17-23, 2011
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 23, 91
January 24-30, 2011
Àwa Yóò Máa Rìn Nínú Ìwà Títọ́ Wa!
OJÚ ÌWÉ 28
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 29, 45
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 3 sí 16
Àwọn ọ̀dọ́ la dìídì kọ àwọn àpilẹ̀kọ wọ̀nyí fún. Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ ṣàlàyé bí àwọn ọ̀dọ́ ṣe lè jẹ́ kí àwọn ìmọ̀ràn tó wà nínú Bíbélì, Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa tọ́ ìṣísẹ̀ àwọn. Èkejì jíròrò bí wọ́n ṣe lè yẹra fún ẹ̀mí ṣohun-tẹ́gbẹ́-ń-ṣe. Ẹ̀kẹta sì jíròrò àwọn ohun tó ṣeé lé bá tí àwọn ọ̀dọ́ lè fi ṣe àfojúsùn wọn.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 àti 5 OJÚ ÌWÉ 24 sí 32
Kọ́ bó o ṣe lè kọ́wọ́ ti Jèhófà Ọlọ́run gẹ́gẹ́ bí ọba aláṣẹ ayé àtọ̀run. Kíyè sí ohun tó túmọ̀ sí láti jẹ́ ẹni tó ń pa ìwà títọ́ mọ́. Ṣàgbéyẹ̀wò ìgbésí ayé Jóòbù tó jẹ́ adúróṣánṣán. Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì ṣàlàyé bó o ṣe lè máa pa ìwà títọ́ rẹ mọ́ bí Jóòbù àtàwọn míì nígbà àtijọ́ ti ṣe, kó o sì rọ̀ mọ́ Jèhófà gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọba Aláṣẹ rẹ.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Jèhófà Ń Gbọ́ Igbe Àwọn Ẹni Rírẹlẹ̀ 17
‘Ẹ Jẹ́ Ká Gbé Àwọn Ọrẹ Ẹbọ Wá fún Jèhófà’ 20
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé 22
‘Àwọn Ohun Tó Ṣe Ti Bá A Lọ ní Tààràtà’ 23