Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 15, 2010
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
January 31, 2011–February 6, 2011
Ẹ Jẹ́ Onítara fún Ìjọsìn Tòótọ́
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 101, 97
February 7-13, 2011
“Ìsinsìnyí Gan-an Ni Àkókò Ìtẹ́wọ́gbà”
OJÚ ÌWÉ 11
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 96, 98
February 14-20, 2011
Kórè Ìbùkún Yanturu Nípasẹ̀ Ọba Tí Ọlọ́run Ń Fi Ẹ̀mí Rẹ̀ Darí!
OJÚ ÌWÉ 16
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 99, 109
February 21-27, 2011
OJÚ ÌWÉ 20
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 75, 116
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 15
Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká rí bí Jésù ṣe lo ojúlówó ìtara, èyí tó jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa láti máa tẹ̀ lé. Àmọ́, kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì gan-an pé ká jẹ́ onítara lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa lásìkò yìí? Báwo ló ṣe jẹ́ pé ìsinsìnyí gan-an ni àkókò ìtẹ́wọ́gbà?
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 16 sí 20
Àkókò tí ìjọba èèyàn ti forí ṣánpọ́n là ń gbé yìí. Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká mọ ìdí tí Jèhófà fi yan Jésù Kristi láti ṣàkóso aráyé àti bí ìtẹríba wa fún Kristi ṣe máa mú ká rí ìbùkún rẹpẹtẹ gbà.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24
Kí nìdí tó fi bá Ìwé Mímọ́ mu tó sì tún jẹ́ ohun yíyẹ pé kí orin kó ipa pàtàkì nínú ìjọsìn wa? Àpilẹ̀kọ yìí máa dáhùn ìbéèrè yìí, á sì tún jẹ́ kí olúkúlùkù wa mọ bá a ṣe lè mú kí ipa tí orin ń kó nínú ìjọsìn wa sunwọ̀n sí i.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Èèyàn Kì Í Dàgbà Jù Láti Sin Ọlọ́run 25
Mo Ti Rí Bí Òtítọ́ Bíbélì Ṣe Lágbára Tó 26
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé 30
Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2010 32