Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 15, 2011
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
May 2-8, 2011
Ẹ̀mí Ọlọ́run Ni Kó O Gbà, Má Ṣe Gba Ẹ̀mí Ayé
OJÚ ÌWÉ 8
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 60, 71
May 9-15, 2011
Ẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Bí Òpin Ti Ń Sún Mọ́lé
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 125, 48
May 16-22, 2011
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 54, 135
May 23-29, 2011
OJÚ ÌWÉ 28
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 65, 43
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 OJÚ ÌWÉ 8 sí 12
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀mí ayé ló ń darí àwọn èèyàn tó wà nínú ayé, ǹjẹ́ ó ṣeé ṣe fún wa láti dá yàtọ̀? Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká mọ bí ẹ̀mí ayé ṣe lè nípa lórí wa. A tún máa jíròrò ohun tá a lè rí kọ́ látinú àpẹẹrẹ Jésù nípa bá a ṣe lè rí ẹ̀mí Ọlọ́run gbà.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2 OJÚ ÌWÉ 12 sí 16
Kí ló túmọ̀ sí láti gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà? Àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ ká rí i pé gbígbẹ́kẹ̀lé Jèhófà kọjá kéèyàn wulẹ̀ ní ìgbàgbọ́ nínú ìlérí tó ṣe nípa ayé tuntun. Ó tún kan pé ká fi tọkàntọkàn fara mọ́ ọ̀nà tí Ọlọ́run fẹ́ ká máa gbà gbé ìgbé ayé wa, ká máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà rẹ̀, ká sì kọ ọ̀nà ayé àti àwọn ìlànà ti ayé sílẹ̀.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3, 4 OJÚ ÌWÉ 24 sí 32
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká rí bí Nóà òun ìdílé rẹ̀ àti Mósè pẹ̀lú Jeremáyà ṣe wà ní ìmúratán láti ṣe iṣẹ́ tí Ọlọ́run gbé lé wọn lọ́wọ́, kí wọ́n lè tipa bẹ́ẹ̀ rí ìmúṣẹ àwọn ìlérí Ọlọ́run. Wo àwọn ẹ̀kọ́ tó o lè rí kọ́ lára àwọn ọkùnrin wọ̀nyí àti ìṣarasíhùwà wọn.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ẹ Má Ṣe Fi Èrò Èké Tan Ara Yín Jẹ
6 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
20 Má Ṣe Kọ Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́ Sílẹ̀ Láé