ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w11 6/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
w11 6/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

June 15, 2011

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

August 1-7, 2011

Ìhìn Rere Tó Yẹ Kí Gbogbo Èèyàn Gbọ́

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÍ A Ó KỌ: 47, 101

August 8-14, 2011

Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Rẹ̀ fún Wa

OJÚ ÌWÉ 11

ÀWỌN ORIN TÍ A Ó KỌ: 18, 91

August 15-21, 2011

“Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run Tí Ń Bẹ Lábẹ́ Àbójútó Yín”

OJÚ ÌWÉ 20

ÀWỌN ORIN TÍ A Ó KỌ: 42, 84

August 22-28, 2011

“Ẹ Ní Ẹ̀mí Ìkanisí fún Àwọn Tí Ń Ṣiṣẹ́ Kára Láàárín Yín”

OJÚ ÌWÉ 24

ÀWỌN ORIN TÍ A Ó KỌ: 123, 53

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1, 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 15

Nínú ìwé Róòmù, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ nípa “ìhìn rere” tó wà fún àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀. Kí ni “ìhìn rere” náà? Àǹfààní wo lo lè rí látinú rẹ̀? Àwọn àpilẹ̀kọ méjì yìí máa jẹ́ kó o ní òye púpọ̀ sí i nípa ẹbọ Jésù àti bí Ọlọ́run ṣe tipasẹ̀ ẹbọ náà fi ìfẹ́ tó ní sí wa hàn, wọ́n á sì tún jẹ́ kí ìmọrírì rẹ pọ̀ sí i fún ẹbọ náà àti ìfẹ́ tí Ọlọ́run fi hàn.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3, 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 28

Àlàyé tá a ṣe nínú àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kí àwọn alàgbà túbọ̀ mọyì àǹfààní tí wọ́n ní láti jẹ́ olùṣọ́ àgùntàn. Bákan náà, a jíròrò àwọn ọ̀nà tí ìjọ lè gbà máa bọ̀wọ̀ fún àwọn alàgbà látọkànwá.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

3 Ṣó Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Ṣe Ìrìbọmi?

16 Ṣé Òótọ́ Ni Ábúráhámù Ní Ràkúnmí?

18 ‘Mú Àwọn Àkájọ Ìwé Wá àti ní Pàtàkì Àwọn Ìwé Awọ’

29 Báwo Lo Ṣe Lè “Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí sí Rere”?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́