Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 15, 2011
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
September 26, 2011–October 2, 2011
OJÚ ÌWÉ 8
October 3-9, 2011
OJÚ ÌWÉ 12
October 10-16, 2011
Jèhófà, “Ọlọ́run Tí Ń Fúnni Ní Àlàáfíà”
OJÚ ÌWÉ 23
October 17-23, 2011
OJÚ ÌWÉ 27
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1, 2 OJÚ ÌWÉ 8 sí 16
Ọ̀pọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ nípa Mèsáyà wà nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù. Wàá mọ ẹni tí Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí náà jẹ́ bó o bá yẹ díẹ̀ lára àwọn àsọtẹ́lẹ̀ náà wò. Àwọn ìsọfúnni inú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí máa wúlò fún ẹ bó o bá wà lóde ẹ̀rí. Ó sì dájú pé ẹ̀kọ́ tó o máa rí kọ́ nínú àwọn àpilẹ̀kọ náà á túbọ̀ gbé ìgbàgbọ́ tó o ní nínú àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Jèhófà ró.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3, 4 OJÚ ÌWÉ 23 sí 31
Ìṣọ̀kan tó wà láàárín àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ò lẹ́gbẹ́, kò sì yẹ ká fọwọ́ yẹpẹrẹ mú irú ìṣọ̀kan bẹ́ẹ̀. Èyí àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí fún wa ní àwọn àpẹẹrẹ látinú Bíbélì tó máa ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ ẹni tó ń wá àlàáfíà. Àpilẹ̀kọ kejì sì ṣàlàyé bá a ṣe lè máa lépa àlàáfíà.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
6 Àwọn Àbá Tó Lè Wúlò fún Yín Nígbà Ìjọsìn Ìdílé àti Ìdákẹ́kọ̀ọ́
17 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
18 Ìpàdé Kan Tó Jẹ́ Mánigbàgbé
22 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé