Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 15, 2011
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
October 24-30, 2011
OJÚ ÌWÉ 7
October 31, 2011–November 6, 2011
Ǹjẹ́ Ò Ń Fi Jèhófà Ṣe Ìpín Rẹ?
OJÚ ÌWÉ 11
November 7-13, 2011
OJÚ ÌWÉ 16
November 14-20, 2011
“Ẹ Sáré . . . Kí Ọwọ́ Yín Lè Tẹ̀ Ẹ́”
OJÚ ÌWÉ 20
November 21-27, 2011
OJÚ ÌWÉ 25
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1, 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 15
Kí ni Jèhófà ní lọ́kàn nígbà tó sọ fún àwọn ọmọ Léfì pé: “Èmi ni ìpín rẹ”? (Núm. 18:20) Ṣé àwọn ọmọ Léfì nìkan ni wọ́n ní àǹfààní yẹn? Lóde òní, ṣé Jèhófà lè jẹ́ ìpín tiwa náà? Bó bá lè jẹ́ ìpín wa, ọ̀nà wo ló lè gbà jẹ́ bẹ́ẹ̀? Àwọn àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ méjì yìí máa sọ̀rọ̀ lórí bí Jèhófà ṣe lè jẹ́ ìpín wa.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3, 4 OJÚ ÌWÉ 16 sí 24
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè borí nínú eré ìje tá à ń sá ká bàa lè gba èrè ìyè àìnípẹ̀kun. Ibo la ti lè rí ìtìlẹ́yìn àti ìṣírí gbà? Àwọn ọ̀fìn àti àwọn ìdíwọ́ wo ló yẹ ká yẹra fún? Kí ló sì máa ràn wá lọ́wọ́ láti máa sá eré náà nìṣó kí ọwọ́ wa lè tẹ èrè náà?
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 5 OJÚ ÌWÉ 25 sí 29
Jèhófà mọ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ olóòótọ́, inú rẹ̀ sì ń dùn sí wọn. Àwọn ànímọ́ wo la nílò kí àjọṣe rere tá a ní pẹ̀lú Jèhófà máa bàa bà jẹ́? Àpilẹ̀kọ yìí máa ran ẹnì kọ̀ọ̀kan wa lọ́wọ́ ká lè ṣàyẹ̀wò irú ẹni tá a jẹ́.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Kíka Bíbélì Lójoojúmọ́ Ti Fún Mi Lókun
30 Ǹjẹ́ O Lè Ṣe Bíi Ti Fíníhásì Bó O Bá Dojú Kọ Àwọn Ipò Tó Nira?