ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w11 10/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
w11 10/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Irọ́ márùn-ún wo làwọn èèyàn máa ń pa mọ́ Ọlọ́run?

WO OJÚ ÌWÉ 4 SÍ 8.

Báwo ni mímọ òtítọ́ nípa Ọlọ́run ṣe lè yí ìgbésí ayé rẹ pa dà?

WO OJÚ ÌWÉ  9.

Ṣé ó yẹ kí wọ́n máa ṣe ìrìbọmi fún àwọn ọmọ ọwọ́?

WO OJÚ ÌWÉ 11.

Kí ló lè mú kí ìdílé rẹ jẹ́ aláyọ̀?

WO OJÚ ÌWÉ 16 SÍ 17.

Kí la lè rí kọ́ nínú àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ àti ìgboyà Ẹ́sítérì?

WO OJÚ ÌWÉ 18.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]

Mẹ́talọ́kan, nǹkan bí ọdún 1500, Flemish School, (16th century)/​H. Shickman Gallery, New York, USA/​The Bridgeman Art Library International

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́