ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w12 2/15 ojú ìwé 1-4
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
w12 2/15 ojú ìwé 1-4

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

February 15, 2012

© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

APRIL 2-8, 2012

Ẹ Wà Lójúfò Bíi Ti Jésù

OJÚ ÌWÉ 3 • ÀWỌN ORIN: 108, 74

APRIL 9-15, 2012

“Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára Gidigidi”

OJÚ ÌWÉ 10 • ÀWỌN ORIN: 101, 92

APRIL 16-22, 2012

Ẹ Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Rere Gbilẹ̀ Nínú Ìjọ

OJÚ ÌWÉ 18 • ÀWỌN ORIN: 20, 75

APRIL 23-29, 2012

Àwọn Tó Wà Nínú Ìdílé Tí Wọ́n Ti Ń Ṣe Ẹ̀sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Lè Láyọ̀

OJÚ ÌWÉ 26 • ÀWỌN ORIN: 76, 56

OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 OJÚ ÌWÉ 3 sí 7

Kí nìdí tí Jésù fi rọ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ pé kí wọ́n wà lójúfò? Àpilẹ̀kọ yìí sọ ọ̀nà mẹ́ta tí Kristi gbà wà lójúfò nígbà tó wà lórí ilẹ̀ ayé. Bá a ṣe ń jíròrò ọ̀kọ̀ọ̀kan lára wọn, a máa rí àwọn ọ̀nà tó dára tá a lè gbà tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2 OJÚ ÌWÉ 10 sí 14

Báwo la ṣe lè jàǹfààní látinú kíkẹ́kọ̀ọ́ nípa bí àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà tó gbé láyé nígbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì ṣe lo ìgboyà? A máa rí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ tá a dìídì kọ láti mú ká jẹ́ onígboyà yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 18 sí 22

Ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ní irú ànímọ́ tàbí ìwà kan tó ti mọ́ ọn lára. Àpilẹ̀kọ yìí sọ bá a ṣe lè mú kí ẹ̀mí rere, tí ń gbéni ró máa gbilẹ̀ nínú ìjọ.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 26 sí 30

Ojoojúmọ́ ni àwọn Kristẹni tó wá látinú ìdílé tí wọ́n ti ń ṣe ẹ̀sìn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ máa ń kojú ìṣòro. Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé bí àwọn tó jẹ́ onígbàgbọ́ ṣe lè mú kí àlàáfíà wà nínú ìdílé kí wọ́n sì mú kó rọrùn fún àwọn tó jẹ́ aláìgbàgbọ́ nínú ìdílé wọn láti wá sínú ìjọsìn tòótọ́.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

8 Wọ́n Fi Ìgboyà Polongo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run!

15 Ìlara Lè Mú Kéèyàn Ní Èròkerò

23 Nátánì—Adúróṣinṣin Tó Gbé Ìjọsìn Mímọ́ Lárugẹ

31 Látinú Àpamọ́ Wa

ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Ní ibùdókọ̀ rélùwéè kan ní ìlú New Delhi, lórílẹ̀-èdè Íńdíà, tí ọkọ̀ rélùwéè tó ń ná ibẹ̀ lóòjọ́ lé ní ọ̀ọ́dúnrún [300], àwọn ará ń wàásù fún àwọn èrò àtàwọn arìnrìn-àjò tó ń wá láti apá ibi gbogbo lórílẹ̀-èdè náà

ÍŃDÍÀ

IYE ÈÈYÀN

1,224,614,000

IYE AKÉDE

33,182

IYE TÍ ÀWỌN AKÉDE FI PỌ̀ SÍ I

Ìdá 5

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́