Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Kí Ni Bíbélì Fi Yàtọ̀ sí Àwọn Ìwé Yòókù?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Bíbélì Yàtọ̀ sí Àwọn Ìwé Yòókù?
4 Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Máa Ń Ṣẹ Pátápátá
5 Òótọ́ Ni Ìtàn inú Bíbélì Kì Í Ṣe Àlọ́
6 Ohun Tí Bíbélì Sọ Bá Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Mu
7 Gbogbo Ìwé inú Bíbélì Wà Níṣọ̀kan
9 “Èyí Túmọ̀ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun”
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
14 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Ọkàn Rẹ Yóò . . . Tẹ̀ Ba Mọ́lẹ̀ Lórí Mi”
15 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Wàásù Láti Ilé Dé Ilé?
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Lo Orúkọ Ọlọ́run?
24 Lẹ́tà Kan Láti Orílẹ̀-Èdè Ireland
26 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
30 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ó Kọ́kọ́ Ṣàìgbọràn àmọ́ Nígbà Tó Yá Ó Ṣègbọràn
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
10 Coverdale Ẹni Tó Túmọ̀ Bíbélì Odindi Tí Wọ́n Kọ́kọ́ Tẹ̀ Lédè Gẹ̀ẹ́sì
18 Ìjàkadì Nítorí Ìhìn Rere Ní Ìlú Tẹsalóníkà
22 Ohun Téèyàn Lè Ṣe Tí Owó Tó Ń Wọlé Fúnni Bá Dín Kù
27 Ṣé Òótọ́ Ni Pé Nǹkan Kan Wà Tí Kò Ṣeé Ṣe?