ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w12 6/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
w12 6/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

June 15, 2012

© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

JULY 30, 2012–AUGUST 5, 2012

Jèhófà Ni “Olùṣí Àwọn Àṣírí Payá”

OJÚ ÌWÉ 7 • ÀWỌN ORIN: 114, 117

AUGUST 6-12, 2012

Jèhófà Ṣí Àwọn Ohun Tí Ó “Gbọ́dọ̀ Ṣẹlẹ̀ Láìpẹ́” Payá

OJÚ ÌWÉ 14 • ÀWỌN ORIN: 116, 54

AUGUST 13-19, 2012

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Fi Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà sí Ipò Àkọ́kọ́?

OJÚ ÌWÉ 20 • ÀWỌN ORIN: 66, 103

AUGUST 20-26, 2012

‘Ẹ̀mí Mímọ́ Darí Wọn’

OJÚ ÌWÉ 25 • ÀWỌN ORIN: 37, 95

OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 18

Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo ló lè mú kó o lóye àwọn nǹkan tó ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ nínú ayé? Nínú àwọn àpilẹ̀kọ méjì yìí a óò ṣàgbéyẹ̀wò àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tó dá lórí ère arabarìbì inú ìwé Dáníẹ́lì orí 2 àti ẹranko ẹhànnà náà pẹ̀lú ère rẹ̀ nínú ìwé Ìṣípayá orí 13 àti 17. Àwọn ìran yìí jẹ́ ká mọ ohun púpọ̀ nípa àwọn nǹkan tó ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24

Bí ẹnì kan bá ṣe ìrìbọmi, ńṣe ló ń fi hàn pé ṣíṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ni òun máa fi sí ipò àkọ́kọ́ ní ìgbésí ayé òun. Tá a bá n ṣe àṣàrò lórí àwọn ìpinnu táwọn ìránṣẹ́ Jèhófà tí wọ́n jẹ́ olùfọkànsìn ṣe láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì, ó lè mú ká fẹ́ láti ṣe àyẹ̀wò bí a ṣe ń lo àkókò wa, okun wa àtàwọn ohun ìní wa.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 25 sí 29

Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé bí ‘ẹ̀mí mímọ́ ṣe darí’ àwọn wòlíì àti àwọn tó kọ Bíbélì àti ìdí tó fi yẹ kó dá wa lójú pé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì. (2 Pét. 1:21) Ó tún ṣàlàyé ohun tó lè mú ká máa mọrírì Bíbélì.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

3“Àṣírí” Tí A Kọ́ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Mímọ́

12A Ṣí Àwọn Ọba Mẹ́jọ Payá

19Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

30Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n Máa Wá “Ìdarí Jíjáfáfá””

32Inú Rere Máa Ń Yí Ìwà Kíkorò Pa Dà

ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Kí àwọn ẹlẹ́rìí lè dé ọ̀dọ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn bó bá ti lè ṣeé ṣe tó, wọ́n máa ń lọ wàásù fún wọn láwọn ibi tí wọ́n bá wà àti ní ipòkípò tí wọ́n bá bá wọn. Lára irú àwọn ibi bẹ́ẹ̀ ni Damnoen Saduak tí wọ́n ti máa ń nájà lórí omi.

THAILAND

IYE ÈÈYÀN

66,720,000

IYE AKÉDE

3,423

ÀWỌN AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ DÉÉDÉÉ

824

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́