Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 15, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
AUGUST 27, 2012–SEPTEMBER 2, 2012
Jẹ́ Kí Jèhófà Ṣamọ̀nà Rẹ Síbi Tí Ojúlówó Òmìnira Wà
OJÚ ÌWÉ 7 • ÀWỌN ORIN: 107, 27
SEPTEMBER 3-9, 2012
Máa Sin Ọlọ́run Tí Ń Sọni Di Òmìnira
OJÚ ÌWÉ 12 • ÀWỌN ORIN: 120, 129
SEPTEMBER 10-16, 2012
“Ta Ni Èmi Yóò Ní Ìbẹ̀rùbojo Fún?”
OJÚ ÌWÉ 22 • ÀWỌN ORIN: 33, 45
SEPTEMBER 17-23, 2012
“Jèhófà Kan Ṣoṣo” Ń Kó Ìdílé Rẹ̀ Jọ
OJÚ ÌWÉ 27 • ÀWỌN ORIN: 53, 124
OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 16
Jèhófà fẹ́ kí gbogbo ẹ̀dá olóye tí òun dá gbádùn òmìnira tó ga jù lọ. Nínú àwọn àpilẹ̀kọ yìí, fiyè sí bí Jèhófà ṣe ń kọ́ wa ká lè wà lómìnira. Sì tún kíyè sí bí Sátánì ṣe ń gbìyànjú láti gba òmìnira wa lọ́wọ́ wa nípa fífi ẹ̀tàn mú ká gbà pé inú ayé la ti lè rí òmìnira.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 22 sí 26
Kí nìdí tá a fi ń fi ìgboyà bá iṣẹ́ ìwàásù wa nìṣó bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n túbọ̀ ń ṣàtakò sí wa, tí ipò ọrọ̀ ajé sì ń burú sí i? Ìwé Sáàmù 27 tá a gbé àpilẹ̀kọ yìí kà ṣàlàyé díẹ̀ lára àwọn ìdí náà.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 27 sí 31
Iṣẹ́ àbójútó Ọlọ́run ń bá a nìṣó títí dòní. Tá a bá ṣe àyẹ̀wò díẹ̀ lára lẹ́tà tí Pọ́ọ̀lù kọ sí àwọn ará Éfésù, ó máa jẹ́ ká lóye ohun tí iṣẹ́ àbójútó yìí wà fún, ká sì ṣiṣẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú rẹ̀.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Ecuador
17Jèhófà Kọ́ Mi Láti Ṣe Ìfẹ́ Rẹ̀
32“Bí Mo Ṣe Fẹ́ Kó Rí Bẹ́ẹ̀ Náà Ló Rí”
ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Wọ́n ń fi Èdè Adití Lọ́nà ti Brazil wàásù ìhìn rere ní ìlú Rio de Janeiro ní Comunidade da Rocinha
ÀWỌN TÓ Ń FI ÈDÈ ADITÍ LỌ́NÀ TI BRAZIL WÀÁSÙ
IYE ÌJỌ
358
IYE ÀWÙJỌ
460
IYE ÀYÍKÁ
18