Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. All rights reserved.
Ìwà Ìbàjẹ́—Ǹjẹ́ Ó Lè Dópin?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Báwo Ni Ìwà Ìbàjẹ́ Ṣe Gbilẹ̀ Tó?
4 Kí Nìdí Tí Ìwà Ìbàjẹ́ Kò Fi Kásẹ̀ Nílẹ̀?
5 Ǹjẹ́ Èèyàn Lè Jẹ́ Olóòótọ́ Nínú Ayé Oníwà Ìbàjẹ́ Yìí?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ǹjẹ́ O Lè Wà Láàyè Títí Láé?
18 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé sì Jókòó”
19 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—“Obìnrin Títayọ Lọ́lá”
25 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ṣé Ó Dìgbà Téèyàn Bá Lọ́kọ Tàbí Téèyàn Bá Láya Kó Tó Lè Láyọ̀?
26 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Má Ṣe Máa Wá Ipò Ńlá!
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ