Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. All rights reserved.
Ìbéèrè Wo Lo Máa Fẹ́ Bi Ọlọ́run?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Ó Tọ́ Ká Máa Bi Ọlọ́run Ní Ìbéèrè?
4 Ìbéèrè Kìíní: Ìwọ Ọlọ́run, Kí Nìdí Tó O Fi Dá Mi Sáyé?
6 Ìbéèrè Kejì: Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ sí Mi Nígbà Tí Mo Bá Kú?
8 Ìbéèrè Kẹta: Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Jẹ́ Kí Ìyà Máa Jẹ Mí?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ǹjẹ́ Ọlọ́run Yóò Fún Wa Ní Ìjọba Kan Tó Máa Ṣàkóso Gbogbo Ayé?
18 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀ —Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Nípa Gbèsè
22 Sún Mọ́ Ọlọ́run —‘Kí Ni Ohun Tí Jèhófà Ń Béèrè Láti Ọ̀dọ̀ Rẹ?’
23 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ṣé Ẹni Tó Bá Lóun Ní Ìgbàgbọ́ Kàn Ń Tan Ara Rẹ̀ Jẹ Ni?
24 Ẹ̀kọ́ Bíbélì
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
26 Bí Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Lákòókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì—Olùṣọ́ Àgùntàn
29 Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Gbèjà Ẹ̀tọ́ Ẹni Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ̀ Kò Jẹ́ Kó Ṣiṣẹ́ Ológun