Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 15, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. All rights reserved.
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
JANUARY 28, 2013–FEBRUARY 3, 2013
OJÚ ÌWÉ 4 • ÀWỌN ORIN: 115, 45
FEBRUARY 4-10, 2013
OJÚ ÌWÉ 9 • ÀWỌN ORIN: 62, 125
FEBRUARY 11-17, 2013
OJÚ ÌWÉ 19 • ÀWỌN ORIN: 107, 40
FEBRUARY 18-24, 2013
Àwọn “Olùgbé fún Ìgbà Díẹ̀” Ń Sin Jèhófà ní Ìṣọ̀kan
OJÚ ÌWÉ 24 • ÀWỌN ORIN: 124, 121
OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1, 2 OJÚ ÌWÉ 4 sí 13
Kí ló lè mú káyé yẹni ní tòótọ́? Àwọn àpilẹ̀kọ yìí fi hàn pé ọ̀pọ̀ èèyàn ò mọ ohun tó ń mú káyé yẹni. A tún máa rí i pe kí ayé lè yẹ wá, ó ṣe pàtàkì pé ká jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run, ká sì gbà láti ṣe iṣẹ́ tó gbé lé wa lọ́wọ́.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3, 4 OJÚ ÌWÉ 19 sí 28
Kí nìdí tá a fi lè sọ pé “olùgbé fún ìgbà díẹ̀” ni àwọn ẹni àmì òróró àti “àwọn àgùntàn mìíràn” tí wọ́n jẹ́ alábàákẹ́gbẹ́ wọn? (Jòh. 10:16; 1 Pét. 2:11) A máa rí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí nínú àwọn àpilẹ̀kọ yìí. Wọ́n tún máa ràn wá lọ́wọ́ láti dúró lórí ìpinnu wa láti máa gbé bí olùgbé fún ìgbà díẹ̀ nínú ayé, ká sì máa ṣiṣẹ́ ìwàásù pẹ̀lú ẹgbẹ́ àwọn ará wa kárí ayé.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ṣé Òótọ́ Ni Bíbélì Ní Agbára Àràmàǹdà?
14 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
29 Ilé Ìṣọ́ Tá A Fi Èdè Gẹ̀ẹ́sì Tó Rọrùn Kọ Kí Nìdí Tá A Fi Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Tẹ̀ Ẹ́?
32 Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2012
ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Ó ju ọ̀kẹ́ márùn-ún [100,000] akéde lọ tó wà ní orílẹ̀-èdè South Korea. Àmọ́, wọ́n ju ọ̀pọ̀ nínú wọn sẹ́wọ̀n torí pé wọn kò dá sí ìṣèlú, wọ́n sì tún kọ̀ láti jagun. Síbẹ̀, wọ́n sapá láti fi lẹ́tà kíkọ wàásù ní ọgbà ẹ̀wọ̀n
SOUTH KOREA
IYE ÈÈYÀN
48,184,000
IYE AKÉDE
100,059
ÀWỌN ARÁKÙNRIN TÍ WỌ́N JÙ SẸ́WỌ̀N LỌ́DÚN TÓ KỌJÁ
731
WÁKÀTÍ TÍ WỌ́N FI Ń WÀÁSÙ LÓṢOOṢÙ
9,000