ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w13 5/1 ojú ìwé 16
  • Òtítọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Òtítọ́
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
w13 5/1 ojú ìwé 16

Òtítọ́

Ibo lo ti lè rí i?

Báwo ni òtítọ́ ṣe lè ṣe ìwọ àti ìdílé rẹ láǹfààní?

A pè ọ́ tayọ̀tayọ̀ kí o wá gbọ́ ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí ní àpéjọ ọlọ́jọ́-mẹ́ta tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe lọ́dún yìí.

ẸṢIN Ọ̀RỌ̀:

‘Òtítọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run!’

a gbé e ka ọ̀rọ̀ tí Jésù sọ nínú Jòhánù 17:17.

ÀWỌN OHUN TÍ A MÁA GBÁDÙN:

Àsọyé alárinrin kan tó máa ṣàlàyé ìdí tí a fi lè gbẹ́kẹ̀ lé Bíbélì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Àkòrí rẹ̀ ni “Kí Ni Òtítọ́?”

A máa wo àwòkẹ́kọ̀ọ́ méjì tó máa jẹ́ kó dà bíi pé ìṣojú wa ni àwọn ìtàn Bíbélì ṣe ṣẹlẹ̀, tá á sì tún kọ́ wa lẹ́kọ̀ọ́.

ÀWỌN WO LA PÈ:

Gbogbo èèyàn la pè. Ọ̀fẹ́ ni, kò sí owó ìwọlé, a kì í sì í gbégbá ọrẹ.

ÀKÓKÒ ÀTI IBI TÍ A TI MÁA ṢE É:

Wá àpéjọ kan tó bá sún mọ́ ẹ, kí o sì wo fídíò tó dá lórí àwọn àpéjọ wa lórí ìkànnì www.jw.org. (Wo abẹ́ NÍPA WA/ÀWỌN ÀPÉJỌ)

Lọ wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ yìí lórí ìkànnì www.jw.org. (Wo Àbẹ́ ÀWỌN ÌTẸ̀JÁDE/ÀWỌN ÌWÉ ŃLÁ ÀTÀWỌN ÌWÉ PẸLẸBẸ)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́