Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 15, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
AUGUST 5-11, 2013
Túbọ̀ Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Àwọn Ànímọ́ Jèhófà
AUGUST 12-18, 2013
Jẹ́ Ọ̀làwọ́ Kó O Sì Máa Fòye Báni Lò Bíi Ti Jèhófà
AUGUST 19-25, 2013
Jẹ́ Adúróṣinṣin Kó O Sì Máa Dárí Jini Bíi Ti Jèhófà
AUGUST 26, 2013–SEPTEMBER 1, 2013
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Túbọ̀ Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Àwọn Ànímọ́ Jèhófà
▪ Jẹ́ Ọ̀làwọ́ Kó O Sì Máa Fòye Báni Lò Bíi Ti Jèhófà
▪ Jẹ́ Adúróṣinṣin Kó O Sì Máa Dárí Jini Bíi Ti Jèhófà
Ọ̀pọ̀ Kristẹni ló rò pé ànímọ́ pàtàkì mẹ́rin péré ni Jèhófà ní. Ṣùgbọ́n, àpilẹ̀kọ mẹ́ta yìí á jẹ́ ká túbọ̀ mọyì àwọn ànímọ́ Jèhófà mìíràn tí a kì í sábà jíròrò. Nígbà tá a bá ń jíròrò ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ànímọ́ náà, a máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí: Kí ló túmọ̀ sí? Báwo ni Jèhófà ṣe máa ń fi hàn? Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jèhófà?
▪ Jẹ́ Kí Amọ̀kòkò Tí Kò Lẹ́gbẹ́ Náà Mọ Ẹ́
Nígbà tí Ìwé Mímọ́ ń sọ̀rọ̀ nípa àṣẹ tí Jèhófà ní lórí àwa èèyàn, ó pe Jèhófà ní “Ẹni tí ó mọ wá.” (Aísá. 64:8) Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé bí Amọ̀kòkò Tí Kò Lẹ́gbẹ́ náà ṣe mọ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kan àtàwọn orílẹ̀-èdè kan láyé àtijọ́. Ó tún sọ bá a ṣe lè jàǹfààní látinú bí Jèhófà ṣe ń mọ wá lóde òní.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Jèhófà Bù Kún Mi Gan-an Torí Pé Mo Ṣègbọràn Sí I
22 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
29 Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Máa Tu “Ọkàn Tí Àárẹ̀ Mú” Lára
ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Àwọn akéde yìí ń ṣe ìjẹ́rìí òpópónà ní gbàgede kan nílùú Frankfurt, lórílẹ̀-èdè Jámánì
JÁMÁNÌ
IYE ÈÈYÀN
81,751,600
IYE ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
162,705
ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
74,466
ÀWỌN TÓ WÁ SÍ ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI LỌ́DÚN 2012
265,407