Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 1, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
KÓKÓ Ọ̀RỌ̀
Àwòrán Oníhòòhò—Ó Léwu Àbí Kò Léwu? 3
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 8
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Kí Nìdí Tí Bíbélì Fi Sọ̀rọ̀ Nípa Àwọn Kan Àmọ́ Tí Kò Dárúkọ Wọn? 10
Sún Mọ́ Ọlọ́run—‘Àwọn Ànímọ́ Rẹ̀ Tí A Kò Lè Rí Ṣe Kedere’ 11
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ọlọ́run Pa Nóà “Mọ́ Láìséwu Pẹ̀lú Àwọn Méje Mìíràn” 12
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN Ń BÉÈRÈ NÍPA ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ—Tí Ẹnì Kan Tó Ti Fi Ìjọ Yín Sílẹ̀ Bá Pa Dà Wá, Ṣé Ẹ Kì Í Ta Á Nù?