Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 1, 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
KÓKÓ Ọ̀RỌ̀
Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
OJÚ ÌWÉ 3-7
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ka Bíbélì? 3
Ìròyìn Ayọ̀ fún Gbogbo Èèyàn 7
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Bó O Ṣe Lè Máa Gbé Ayé Rẹ Lọ Lẹ́yìn Ìkọ̀sílẹ̀ 8
Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Jèhófà Dárí Jì Yín Fàlàlà” 11
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Èèyàn Pa Dà 12
Báwo Ni Àwọ̀ Ṣe Ń Nípa Lórí Rẹ? 14
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN Ń BÉÈRÈ NÍPA ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ—Kí Nìdí Tí Ẹ Fi Ń Lọ Láti Ilé Dé Ilé?