ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w14 1/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Ìsọ̀rí
  • Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
w14 1/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

January 15, 2014

© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.

Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

MARCH 3-9, 2014

Sin Jèhófà, Ọba Ayérayé

OJÚ ÌWÉ 7 • ORIN: 106, 46

MARCH 10-16, 2014

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ìṣàkóso Ìjọba Ọlọ́run—Báwo Ló Ṣe Kàn Ọ́?

OJÚ ÌWÉ 12 • ORIN: 97, 101

MARCH 17-23, 2014

Bó O Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Nígbà Ọ̀dọ́

OJÚ ÌWÉ 17 • ORIN: 41, 89

MARCH 24-30, 2014

Bá A Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Kí Àwọn Ọjọ́ Oníwàhálà Tó Dé

OJÚ ÌWÉ 22 • ORIN: 54, 17

MARCH 31, 2014–APRIL 6, 2014

“Kí Ìjọba Rẹ Dé”—Àmọ́, Nígbà Wo?

OJÚ ÌWÉ 27 • ORIN: 108, 30

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

▪ Sin Jèhófà, Ọba Ayérayé

Àpilẹ̀kọ yìí máa mú kó túbọ̀ ṣe kedere pé Ọba ni Jèhófà lọ́jọ́ gbogbo, ó sì máa jẹ́ ká mọ bó ṣe ń ṣàkóso àwọn áńgẹ́lì tó dá sókè ọ̀run àti àwa èèyàn tó dá sórí ilẹ̀ ayé. Ó tún máa fún wa níṣìírí láti tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn ará ìgbàanì tí wọ́n yàn láti sin Jèhófà, Ọba ayérayé.

▪ Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ìṣàkóso Ìjọba Ọlọ́run —Báwo Ló Ṣe Kàn Ọ́?

Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká túbọ̀ mọrírì àwọn nǹkan tí Ìjọba Mèsáyà ti gbé ṣe ní ọgọ́rùn-ún ọdún àkọ́kọ́ tí Ìjọba Ọlọ́run ti ń ṣàkóso. Ó tún máa jẹ́ kí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa rí ìdí tó fi yẹ ká máa bá a nìṣó láìyẹsẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọmọ abẹ́ Ìjọba Ọlọ́run, ó sì máa mú ká fẹ́ láti ṣe àṣàrò lórí ohun tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wa ti ọdún 2014 túmọ̀ sí ní kíkún.

▪ Bó O Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Nígbà Ọ̀dọ́

▪ Bá A Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Kí Àwọn Ọjọ́ Oníwàhálà Tó Dé

Kí ni màá fi ìgbésí ayé mi ṣe? Ìbéèrè tó ṣe pàtàkì lèyí jẹ́ fún ẹnikẹ́ni tó bá ti ya ara rẹ̀ sí mímọ́ fún Jèhófà. Nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, a máa jíròrò àwọn ìlànà tó lè tọ́ àwọn ọ̀dọ́ tó jẹ́ Kristẹni sọ́nà kí wọ́n lè sin Ọlọ́run ní kíkún. A óò tún jíròrò ọ̀pọ̀ àǹfààní tí àwọn àgbà tó jẹ́ Kristẹni ní láti mú iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn gbòòrò sí i.

▪ “Kí Ìjọba Rẹ Dé”—Àmọ́, Nígbà Wo?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ni ò lè pọkàn pọ̀ lóde òní torí bí ipò nǹkan ṣe rí tàbí nítorí ohun tó gba àwọn fúnra wọn lọ́kàn. Àpilẹ̀kọ yìí máa jíròrò ẹ̀rí mẹ́ta tó mú kó dá àwa Kristẹni lójú pé Ìjọba Ọlọ́run máa tó fòpin sí ètò búburú yìí.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

3 Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà

32 Ìpinnu Tí Mo Ṣe Nígbà Tí Mo Wà ní Kékeré

ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Ní ìlú Lviv, wọ́n ń wàásù fún àwọn tó ti ilẹ̀ òkèèrè wá kàwé ní yunifásítì

UKRAINE

IYE ÈÈYÀN

45,561,000

AKÉDE

150,887

Ìjọ 1,737 àti àwùjọ 373 ló wà ní orílẹ̀-èdè yìí. Lára èdè 15 táwọn ará ń lò níbẹ̀ ni èdè Hungarian, Romanian, Russian, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Rọ́ṣíà àti èdè Ukrainian

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́