Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 15, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
JULY 7-13, 2014
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa ‘Dá Ẹnì Kọ̀ọ̀kan Lóhùn’?
JULY 14-20, 2014
Máa Fi Ìlànà Pàtàkì Náà Sílò Lóde Ẹ̀rí
JULY 21-27, 2014
OJÚ ÌWÉ 21 • ORIN: 125, 53
JULY 28, 2014–AUGUST 3, 2014
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa ‘Dá Ẹnì Kọ̀ọ̀kan Lóhùn’?
▪ Máa Fi Ìlànà Pàtàkì Náà Sílò Lóde Ẹ̀rí
Tá a bá wà lóde ẹ̀rí, àwọn èèyàn sábà máa ń bi wá láwọn ìbéèrè tó ta kókó. Àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí jíròrò ọ̀nà mẹ́ta tá a lè gbà dá wọn lóhùn lọ́nà táá yí wọn lérò pa dà. (Kól. 4:6) Àpilẹ̀kọ kejì jẹ́ ká rí ọ̀nà tó yẹ kí ọ̀rọ̀ Jésù tó wà nínú Mátíù 7:12 gbà kan iṣẹ́ ìwàásù wa.
▪ Ọlọ́run Ètò Ni Jèhófà
▪ Ǹjẹ́ Ò Ń Bá Ètò Jèhófà Rìn Bó Ṣe Ń Tẹ̀ Síwájú?
Látilẹ̀ wá ni Jèhófà ti máa ń mú kí àwọn èèyàn rẹ̀ wà létòlétò. Nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, a máa kẹ́kọ̀ọ́ ohun tí Ọlọ́run fẹ́ kí àwa èèyàn rẹ̀ ṣe. Bákan náà, a máa rí ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká dúró ti ètò tí Jèhófà ń lò lórí ilẹ̀ ayé lónìí láìyẹsẹ̀.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 ‘Oúnjẹ Mi Ni Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run’
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Àwọn ará ń wàásù ní ọjá tí wọ́n ti ń ta ẹja lẹ́bàá ọ̀nà. Ó lé ní ogún [20] èdè tí wọ́n ń sọ ní erékùṣù yìí
SAIPAN
IYE ÈÈYÀN
48,220
IYE AKÉDE
201
AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ DÉÉDÉÉ
32
AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ OLÙRÀNLỌ́WỌ́
76
Àwọn tó wá síbi ìrántí ikú Kristi lọ́dún 2013 jẹ́ 570