Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 15, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
SEPTEMBER 1-7, 2014
“Jèhófà Mọ Àwọn Tí Í Ṣe Tirẹ̀”
SEPTEMBER 8-14, 2014
Àwọn Èèyàn Jèhófà “Kọ Àìṣòdodo Sílẹ̀ Ní Àkọ̀tán”
SEPTEMBER 15-21, 2014
SEPTEMBER 22-28, 2014
OJÚ ÌWÉ 28 • ORIN: 102, 103
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ “Jèhófà Mọ Àwọn Tí Í Ṣe Tirẹ̀”
▪ Àwọn Èèyàn Jèhófà “Kọ Àìṣòdodo Sílẹ̀ Ní Àkọ̀tán”
Àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí ṣe àrúnkúnná ohun tí Bíbélì sọ nínú 2 Tímótì 2:19, wọ́n sì jẹ́ ká rí bí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣe tan mọ́ àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà ayé Mósè. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ kí àwa Kristẹni mọ bí a ṣe lè fi hàn pé a ‘jẹ́ ti Jèhófà’ àti pé à ń “kọ àìṣòdodo sílẹ̀ ní àkọ̀tán.”
▪ “Ẹ̀yin Ni Ẹlẹ́rìí Mi”
▪ “Ẹ Ó sì Jẹ́ Ẹlẹ́rìí Mi”
Nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, a máa jíròrò bó ti ṣe pàtàkì tó pé kéèyàn máa jẹ́ orúkọ náà, Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Wàá rí i bó ṣe jẹ́ ohun àmúyangàn pé à ń jẹ́rìí nípa Jèhófà àti Jésù, èyí tó ń mú ká máa fìtara ṣe iṣẹ́ ìwàásù ká sì máa fi ìwà mímọ́ wa yin Ọlọ́run àti Kristi lógo.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Àwọn arábìnrin méjì yìí ń lo ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? láti wàásù fún àwọn obìnrin méjì kan tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà Ndebele, tí wọ́n wọ aṣọ ìbílẹ̀, tí wọ́n sì jókòó níwájú ìta. Bí ilé táwọn Ndebele ń kọ́ sí abúlé ṣe máa ń rí nìyí. Tá a bá sì dá àwọn èèyàn tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè South Africa sí ọgọ́rùn-ún, àwọn Ndebele ló kó ìdá méjì
SOUTH AFRICA
IYE ÈÈYÀN
50,500,000
GÓŃGÓ AKÉDE
94,101
ÀWỌN AKÉDE TÓ Ń SỌ ÈDÈ NDEBELE
1,003