Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 1, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ìjọba Ọlọ́run—Àǹfààní Wo Lo Máa Ṣe Ẹ́?
OJÚ ÌWÉ 3-9
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ìjọba Ọlọ́run? 3
Ìjọba Ọlọ́run—Kí Nìdí Tó fi Ṣe Pàtàkì Gan-an sí Jésù? 4
Ìjọba Ọlọ́run—Àǹfààní Tó Máa Ṣe Ẹ́ 8
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan —Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀? 10
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà 14
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN OHUN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ—Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Gbàdúrà? Ṣé Ọlọ́run Máa Dáhùn Àdúrà Mi?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ))