Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 15, 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
DECEMBER 29, 2014–JANUARY 4, 2015
Àjíǹde Jésù—Àǹfààní Wo Ló Ṣe Wá?
JANUARY 5-11, 2015
OJÚ ÌWÉ 8 • ORIN: 119, 17
JANUARY 12-18, 2015
A Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́ Nínú Gbogbo Ìwà Wa
JANUARY 19-25, 2015
“Àwọn Ènìyàn Tí Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Wọn”
JANUARY 26, 2015–FEBRUARY 1, 2015
“Nísinsìnyí Ẹ Jẹ́ Ènìyàn Ọlọ́run”
OJÚ ÌWÉ 23 • ORIN: 112, 101
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Àjíǹde Jésù—Àǹfààní Wo Ló Ṣe Wá?
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìdí tó fi dá wa lójú pé Ọlọ́run jí Jésù dìde, pé ó sì wà láàyè báyìí. Àpilẹ̀kọ yìí á tún jẹ́ ká rí bí àjíǹde Kristi sí ìyè àìleèkú ní ọ̀run ṣe yẹ kó nípa lórí wa àti lórí bá a ṣe ń polongo Ìjọba Ọlọ́run.
▪ Ìdí Tá A Fi Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́
▪ A Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́ Nínú Gbogbo Ìwà Wa
Orí ìwé Léfítíkù la gbé àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí kà, wọ́n sì jẹ́ ká mọ ìdí tí Jèhófà fi ní káwọn èèyàn rẹ̀ jẹ́ mímọ́ àti bá a ṣe lè máa jẹ́ mímọ́. A tún jíròrò àwọn ọ̀nà tá a lè gbà máa jẹ́ mímọ́ nínú gbogbo ìwà wa.
▪ “Àwọn Ènìyàn Tí Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Wọn”
▪ “Nísinsìnyí Ẹ Jẹ́ Ènìyàn Ọlọ́run”
Ó ṣòro fún díẹ̀ lára àwọn tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láti gbà pé ètò kan ṣoṣo ni Ọlọ́run ní. Wọ́n rò pé òótọ́ inú nìkan ti tó láti ṣe ohun tó wu Ọlọ́run, láìka ìsìn yòówù ká máa ṣe sí. Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí máa jẹ́ ká rí bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká mọ àwọn èèyàn Jèhófà ká sì jọ máa sìn ín.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Àwọn akéde Ìjọba Ọlọ́run ń wàásù ní ìlú Santiago de Cuba. Ìlú yìí ni ìlú kejì tó tóbi jù lọ ní erékùṣù náà, ó sì gbajúmọ̀ gan-an torí orín tí wọ́n máa ń kọ àti ijó ìbílẹ̀ tí wọ́n máa ń jó
CUBA
IYE ÈÈYÀN
11,163,934
IYE AKÉDE
96,206
IYE AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ DÉÉDÉÉ
9,040