Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 15, 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
APRIL 6-12, 2015
Ẹ Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ àti Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ Bíi Ti Jésù
APRIL 13-19, 2015
Ẹ Jẹ́ Onígboyà Kẹ́ Ẹ sì Máa Lo Ìfòyemọ̀ Bíi Ti Jésù
APRIL 20-26, 2015
Mímúra Àwọn Orílẹ̀-Èdè Sílẹ̀ fún “Ẹ̀kọ́ Jèhófà”
APRIL 27, 2015–MAY 3, 2015
Jèhófà Ń Darí Iṣẹ́ Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Tí À Ń Ṣe Kárí Ayé
OJÚ ÌWÉ 24 • ORIN: 103, 66
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Ẹ Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ àti Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ Bíi Ti Jésù
▪ Ẹ Jẹ́ Onígboyà Kẹ́ Ẹ sì Máa Lo Ìfòyemọ̀ Bíi Ti Jésù
Bíbélì gbà wá níyànjú pé ká tẹ̀ lé ìṣísẹ̀ Jésù pẹ́kípẹ́kí. (1 Pét. 2:21) Àmọ́ ǹjẹ́ àwa èèyàn aláìpé lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù délẹ̀délẹ̀? Àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí jíròrò bá a ṣe lè jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ àti oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ bíi ti Jésù. Àpilẹ̀kọ kejì máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè jẹ́ onígboyà, ká sì lo ìfòyemọ̀ bíi ti Jésù.
▪ Mímúra Àwọn Orílẹ̀-Èdè Sílẹ̀ fún “Ẹ̀kọ́ Jèhófà”
▪ Jèhófà Ń Darí Iṣẹ́ Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Tí À Ń Ṣe Kárí Ayé
Àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí jíròrò bí Jèhófà ṣe jẹ́ káwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní lè wàásù ìhìn rere náà. Nínú àpilẹ̀kọ kejì, a máa jíròrò àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ lóde òní tó mú ká lè polongo Ìjọba náà dé ọ̀dọ̀ àwọn tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí òtítọ́ kárí ayé.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ẹ̀bùn Pàtàkì Kan Tó Wà fún Àwọn Ará Japan
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Àwọn akéde ń fi ìwé ìròyìn Jí! lọni lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ilé-dé-ilé ní erékùṣù Bali. Wọ́n ń gbádùn báwọn èèyàn orílẹ̀-èdè Indonesia ṣe nífẹ̀ẹ́ àlejò
INDONESIA
IYE ÈÈYÀN
237,600,000
IYE AKÉDE
24,521
IYE ÀWỌN AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ DÉÉDÉÉ
2,472
Àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe 369 ló ń sìn ní erékùṣù 28 ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀