Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 15, 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
JUNE 29, 2015–JULY 5, 2015
JULY 6-12, 2015
O Lè Bá Sátánì Jà—Kó o sì Borí!
JULY 13-19, 2015
Wọ́n “Rí” Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Ṣèlérí
JULY 20-26, 2015
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Ṣọ́ra!—Sátánì Fẹ́ Pa Ọ́ Jẹ
▪ O Lè Bá Sátánì Jà—Kó o sì Borí!
Bíbélì sọ pé Sátánì ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tí ń ké ramúramù, ó ń wá ọ̀nà láti pani jẹ. Ó lágbára, ìkà ni, ó sì tún jẹ́ atannijẹ. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ka rí ìdí to fi yẹ ká dúró gbọn-in gbọn-in lòdì sí ọ̀tá búburú yìí. Wọ́n á tún jẹ́ ka mọ bí a ṣe lè dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ àwọn ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ tó fi ń tanni jẹ.
▪ Wọ́n “Rí” Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Ṣèlérí
▪ Ẹ Fara Wé Ẹni Tó Ṣèlérí Ìyè Àìnípẹ̀kun
A lè fọgbọ́n lo ẹ̀bùn tí Ọlọ́run fún wa tó jẹ́ ká lè fọkàn yàwòrán àwọn ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀ lójú wa rí, a sì lè ṣì ẹ̀bùn náà lò. Nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, ìjíròrò wa máa dá lórí ọ̀kan-ò-jọ̀kan àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn. A máa kọ́ bá a ṣe lè lo ìgbàgbọ́ tá a bá ń fọkàn yàwòrán àwọn ohun tí a kò tíì rí, tó sì máa jẹ́ ká ní ìfẹ́, inú rere, ọgbọ́n àti ayọ̀ bíi ti Jèhófà.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ìfẹ́ Tí Mo Ní fún Ọlọ́run Látìbẹ̀rẹ̀ Mú Kí N Lè Fara Dà Á
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Àwọn arákùnrin méjì ń kọ́ onílé kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
ARMENIA
IYE ÈÈYÀN
3,026,900
IYE AKÉDE
11,143
ÀWỌN AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ DÉÉDÉÉ
2,205
23,844
Iye àwọn tó wà sí Ìrántí Ikú Kristi ní April 14, 2014 ju ìlọ́po méjì àwọn akéde tó ń ròyìn déédéé lọ