Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 15, 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
SEPTEMBER 28, 2015–OCTOBER 4, 2015
Máa Ṣe Àṣàrò Lórí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Tí Jèhófà Ní sí Wa
OJÚ ÌWÉ 9
OCTOBER 5-11, 2015
Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Fífojú Sọ́nà
OJÚ ÌWÉ 14
OCTOBER 12-18, 2015
Máa Gbé Ìgbé Ayé Tó O Máa Gbé Nínú Ayé Tuntun Báyìí
OJÚ ÌWÉ 19
OCTOBER 19-25, 2015
Ṣọ́ Àwọn Tó Ò Ń Bá Kẹ́gbẹ́ ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Máa Ṣe Àṣàrò Lórí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Tí Jèhófà Ní sí Wa
Jèhófà ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí àwọn èèyàn rẹ̀. Àpilẹ̀kọ yìí dá lórí bí Ọlọ́run ṣe ń fi ìfẹ́ yìí hàn. Tó o bá ń ṣe àṣàrò lórí ìfẹ́ tí Jèhófà ní sí ẹ yìí, àjọṣe tó o ní pẹ̀lú rẹ̀ máa lágbára sí i.
▪ Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Fífojú Sọ́nà
▪ Máa Gbé Ìgbé Ayé Tó O Máa Gbé Nínú Ayé Tuntun Báyìí
Kò yẹ ká rò pé Ọlọ́run ò ní mú àwọn ìlérí rẹ̀ ṣẹ torí àwọn àkókò tó ti kọjá. Ẹ̀rí tó fìdí múlẹ̀ wà nínú Bíbélì tí kò fi yẹ ká dẹ́kun láti máa fojú sọ́nà. Àpilẹ̀kọ yìí sọ bá a ṣe lè máa fojú sọ́nà.
▪ Ṣọ́ Àwọn Tó Ò Ń Bá Kẹ́gbẹ́ ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí
Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì gan-an pé ká ṣọ́ àwọn tá à ń bá kẹ́gbẹ́ ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn líle koko yìí? Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe bẹ́ẹ̀? A dáhùn àwọn ìbéèrè yìí àti àwọn míì tó fara jọ ọ́ nínú àpilẹ̀kọ yìí.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 “Kí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Erékùṣù Máa Yọ̀”
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Arákùnrin kan ń jẹ́rìí lọ́nà àìjẹ́ bí àṣà ní ìlú Esperanza, ó ń fi fídíò kan láti orí Ìkànnì jw.org han ẹni tó ń bá sọ̀rọ̀
AJẸNTÍNÀ
IYE ÈÈYÀN
42,670,000
IYE AKÉDE
150,171
IYE ÀWỌN AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ DÉÉDÉÉ
18,538
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
126,661
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2014)