Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 15, 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
DECEMBER 28, 2015–JANUARY 3, 2016
Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Sin Jèhófà—Apá Kìíní
OJÚ ÌWÉ 3
JANUARY 4-10, 2016
Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Sin Jèhófà—Apá Kejì
OJÚ ÌWÉ 8
JANUARY 11-17, 2016
OJÚ ÌWÉ 16
JANUARY 18-24, 2016
Ǹjẹ́ O “Nífẹ̀ẹ́ Aládùúgbò Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Ara Rẹ”?
OJÚ ÌWÉ 21
JANUARY 25-31, 2016
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Tí Ìjọba Ọlọ́run Ti Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso!
OJÚ ÌWÉ 26
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Sin Jèhófà—Apá Kìíní
▪ Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Sin Jèhófà—Apá Kejì
Jèhófà ti gbé iṣẹ́ bàǹtà-banta lé àwọn òbí lọ́wọ́, ó ní kí wọ́n kọ́ àwọn ọmọ wọn kí wọ́n lè sin òun. Nínú àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, a máa ṣàlàyé bí àwọn òbí ṣe lè ṣe iṣẹ́ yìí láṣeyọrí nípa lílo mẹ́ta lára àwọn ànímọ́ tí Jésù ní, ìyẹn ìfẹ́, ìrẹ̀lẹ̀ àti òye.
▪ Ọlọ́run Ìfẹ́ Ni Jèhófà
▪ Ǹjẹ́ O “Nífẹ̀ẹ́ Aládùúgbò Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Ara Rẹ”?
Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ máa mú kó ṣe kedere pé Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ìfẹ́. Ó sì tún ṣàlàyé bí Ọlọ́run ṣe ń fìfẹ́ hàn sí aráyé. Nínú àpilẹ̀kọ kejì, a máa jíròrò bí àwa ìránṣẹ́ Jèhófà ṣe lè máa fìfẹ́ hàn sí àwọn aládùúgbò wa.
▪ Ọgọ́rùn-ún Ọdún Tí Ìjọba Ọlọ́run Ti Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso!
Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a ṣàlàyé ohun tá a ti ṣe láti wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run láti ọgọ́rùn-ún ọdún tí Ìjọba Ọlọ́run ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso. Wàá rí díẹ̀ lára àwọn ohun èlò tá a fi wàásù àti ọ̀nà tá a gbà sọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn. Wàá tún mọ̀ nípa ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó gbéṣẹ́ táwọn akéde Ìjọba Ọlọ́run ti ń rí gbà láti àwọn ọdún wọ̀nyẹn wá.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Alábòójútó àyíká kan àtàwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe kan ń rìnrìn-àjò lórí odò Amazon. Wọ́n ń láyọ̀ bí wọ́n ṣe ń polongo ìhìn rere láwọn abúlé àdádó tó wà ní etídò náà àti láwọn ibi tí odò náà ṣàn gbà
BRAZIL
IYE ÈÈYÀN
203,067,835
IYE AKÉDE
794,766
IYE ÀWỌN AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ
84,550
IYE ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2014)