Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
No. 1 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÍ LÈRÒ RẸ?
Ǹjẹ́ ayé yìí máa dùn ún gbé tí àwọn èèyàn bá ń ṣe ohun tí ẹsẹ Bíbélì yìí sọ?
“A ti dàníyàn láti máa hùwà láìṣàbòsí nínú ohun gbogbo.”—Hébérù 13:18.
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí sọ̀rọ̀ nípa bí ìwà ìṣòtítọ́ ṣe kan gbogbo ohun tí à ń ṣe láyé.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Olóòótọ́?
Ṣé Jíjẹ́ Olóòótọ́ Ṣì Bóde Mu? 3
Àkóbá Tí Ìwà Àìṣòótọ́ Lè Ṣe fún Ẹ 4
Àǹfààní Tó Wà Nínú Jíjẹ́ Olóòótọ́ 6
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ǹjẹ́ O Mọ̀? 10
Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan 11
KA ÀPILẸ̀KỌ TÓ KÙ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ)