ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp16 No. 2 ojú ìwé 1
  • Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó Sì Kú?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó Sì Kú?
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2016
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2016
wp16 No. 2 ojú ìwé 1
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́, No. 2 2016 | Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó Sì Kú?

Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó Sì Kú?

No. 2 2016

ÌRÀNTÍ IKÚ JÉSÙ | WEDNESDAY, MARCH 23, 2016

© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

ÌWÉ ÌRÒYÌN Ilé Ìṣọ́ yìí ń gbé Jèhófà Ọlọ́run tó jẹ́ Alákòóso ayé òun ọ̀run ga. Ó ń fi ìhìn rere tu àwọn èèyàn nínú pé, láìpẹ́, Ìjọba Ọlọ́run tó ti ń ṣàkóso ní ọ̀run, yóò fòpin sí gbogbo ìwà ibi, á sì sọ ilẹ̀ ayé di Párádísè. Ìwé ìròyìn yìí ń gbani níyànjú láti nígbàgbọ́ nínú Jésù Kristi tó kú ká lè ní ìyè àìnípẹ̀kun. Jésù sì ti ń ṣàkóso báyìí gẹ́gẹ́ bí Ọba Ìjọba Ọlọ́run. Láti ọdún 1879 la ti ń tẹ ìwé ìròyìn yìí déédéé, kì í sì í dá sí ọ̀ràn ìṣèlú. Orí Bíbélì ni gbogbo ohun tó ń sọ dá lé.

Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títa. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.

Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org.

Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́