Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MARCH 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MAY 2-29, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
BELGIUM
Wọ́n ń kọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba Wijnegem sí ọ̀kan lára àwọn ọ̀nà tí mọ́tò ń gbà jù nílùú Antwerp. Kedere làwọn tó ń gba ojú ọ̀nà yìí kọjá máa ń rí àkọlé JW.ORG tó ti wà níbẹ̀ látìgbà táwọn ará ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ níbẹ̀
IYE ÈÈYÀN
11,132,269
IYE AKÉDE
25,839
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2014)
44,635
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.