Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
APRIL 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MAY 30–JUNE 26, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
KÒLÓŃBÍÀ
Àwọn ará máa ń ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe láti wàásù fáwọn èèyàn Wayuu. Àwọn èèyàn yìí fẹ́ràn láti máa sọ̀rọ̀ nípa Ọlọ́run. Wọ́n máa ń lọ sígboro láti tajà wọn. Wọ́n máa ń gbọ́ ìhìn rere nígboro táwọn ará bá ń wàásù láwọn ibi tí èrò pọ̀ sí
IYE AKÉDE
166,049
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
229,723
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
510,952
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.