Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MAY 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JUNE 27–JULY 31, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
GÁNÀ
Akéde kan ń fi ọ̀kan lára àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú wàásù fáwọn ọmọ iléèwé rẹ̀. Ìlú Ho ló ń gbé ní ìpínlẹ̀ Volta, lórílẹ̀-èdè Gánà
IYE AKÉDE
125,443
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
382,408
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2014)
347,725
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.