Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JUNE 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 1-28, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
TRINIDAD
Ọ̀pọ̀ àwọn abúlé tí wọ́n ti ń pẹja ló wà ní etíkun Trinidad àti Tobago. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń lo àǹfààní yẹn láti wàásù fún àwọn apẹja tí wọ́n bá rí
IYE AKÉDE
9,679
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
11,331
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
24,103
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.