Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: OCTOBER 24–NOVEMBER 27, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
FÍJÌ
Inú àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa máa ń dùn bí wọ́n ṣe ń wàásù fáwọn tó ń gbé láwọn abúlé tó wà nítòsí ìlú Suva tí í ṣe olú ìlú Fíjì
IYE ÈÈYÀN
887,027
IYE AKÉDE
3,097
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
11,845
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.