Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
NOVEMBER 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: DECEMBER 26, 2016–JANUARY 29, 2017
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
ÀǸGÓLÀ
Nílùú Benguela, àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lédè àwọn adití. Ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé ni wọ́n ń lò. Inú àwọn akéde mẹ́wàá tó jẹ́ adití dùn gan-an nígbà tí àwọn méjìlélọ́gọ́ta [62] wá síbi Ìrántí Ikú Kristi tí wọ́n ṣe lọ́dún 2015
IYE AKÉDE
115,948
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
502,848
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
529,827
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.