Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
December 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ:JANUARY 30–FEBRUARY 26 2017
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
POTOGÍ
Ọ̀pọ̀ àwọn tó ń rìnrìn-àjò afẹ́ ló máa ń wá sí ìlú Aveiro ní àríwá orílẹ̀-èdè Potogí kí wọ́n lè wá rí ibi tí wọ́n ti ń ṣe iyọ̀. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń wàásù fáwọn tó ń ta iyọ̀ níbẹ̀
IYE AKÉDE
48,840
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
28,687
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
91,472
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.