ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp17 No. 2 ojú ìwé 16
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn” là ń gbé báyìí?
  • Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí àwa èèyàn lọ́jọ́ iwájú?
  • Ṣé Òpin Ayé Ti Sún Mọ́lé?
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
  • Ṣé “Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn” La Wà Yìí?
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • Àwọn Àmì Wo Ló Fi Hàn Pé A Ti Wà Ní “Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn,” Tàbí “Òpin Ayé”?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ète Ọlọrun Yoo Ní Imuṣẹ Laipẹ
    Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
wp17 No. 2 ojú ìwé 16
Àwọn ọmọdé àti àwọn tó dàgbà ń gbádùn ara wọn nínú Párádísè

Àwọn èèyàn tó bá la ọjọ́ ìkẹyìn já máa gbé inú Párádísè

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ṣé “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn” là ń gbé báyìí?

Kí ni ìdáhùn rẹ?

  • Bẹ́ẹ̀ ni

  • Bẹ́ẹ̀ kọ́

  • Kò dá mi lójú

Ohun tí Bíbélì sọ

“Ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn, àwọn àkókò lílekoko tí ó nira láti bá lò yóò wà níhìn-ín.” (2 Tímótì 3:1) Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ inú Bíbélì àtàwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nínú ayé báyìí fi hàn pé “ọjọ́ ìkẹyìn” la wà yìí.

Kí làwọn nǹkan míì tí Bíbélì sọ?

  • Lára ohun tá a máa fi mọ̀ pé a ti wà láwọn ọjọ́ ìkẹyìn ni ogun, ìyàn, ìmìtìtì ilẹ̀ àtàwọn àìsàn gbẹ̀mígbẹ̀mí.​—Mátíù 24:3, 7; Lúùkù 21:11.

  • Ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn, ìwàkiwà àti ìṣekúṣe máa kún ọwọ́ àwọn èèyàn, wọn á sì jìnnà sí Ọlọ́run.​—2 Tímótì 3:2-5.

Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí àwa èèyàn lọ́jọ́ iwájú?

Èrò àwọn kan ni pé . . .

ńṣe ni ayé yìí àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ máa pa run kí ọjọ́ ìkẹyìn tó lọ sópin, àwọn míì sì gbà pé nǹkan ṣì máa dáa. Kí lèrò rẹ?

Ohun tí Bíbélì sọ

“Àwọn olódodo ni yóò ni ilẹ̀ ayé, wọn yóò sì máa gbé títí láé lórí rẹ̀.”​—Sáàmù 37:29.

Kí làwọn nǹkan míì tí Bíbélì sọ?

  • Kí ọjọ́ ìkẹyìn tó lọ sópin, Ọlọ́run máa kọ́kọ́ mú gbogbo ìwà ibi kúrò lórí ilẹ̀ ayé.​—1 Jòhánù 2:17.

  • Ọlọ́run máa sọ ayé di Párádísè.​—Aísáyà 35:1, 6.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn,” ka orí 9 nínú ìwé yìí Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é

Ó tún wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́