ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp17 No. 6 ojú ìwé 16
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí ni Amágẹ́dọ́nì?
  • Ṣé ó ṣeé ṣe kéèyàn la ogun Amágẹ́dọ́nì já?
  • Kí Ni Ogun Amágẹ́dọ́nì?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Amágẹ́dọ́nì Yóò Ṣínà Ayọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Amágẹ́dọ́nì—Kí Ni Àwọn Èèyàn Kan Sọ Pé Ó Jẹ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ìròyìn Ayọ̀ Ni Amágẹ́dọ́nì!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
wp17 No. 6 ojú ìwé 16
“Ogunlọ́gọ̀ ńlá” èèyàn tó la ogun Amágẹ́dọ́nì já

Ogunlọ́gọ̀ ńlá” tí ẹnì kankan kò lè kà, látinú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ló máa la ogun Amágẹ́dọ́nì já

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí ni Amágẹ́dọ́nì?

Àwọn kan gbà gbọ́ pé . . .

ó jẹ́ ogun runlérùnnà tó máa fa ìparun yán-án-yán bá gbogbo ibi láyé. Kí lèrò rẹ?

Ohun tí Bíbélì sọ

Amágẹ́dọ́nì jẹ́ ibi ìṣàpẹẹrẹ fún “ogun ọjọ́ ńlá Ọlọ́run Olódùmarè,” tí Ọlọ́run máa fi mú àwọn ẹni ibi kúrò.​—Ìṣípayá 16:14, 16.

Kí làwọn nǹkan míì tí Bíbélì sọ?

  • Ọlọ́rn máa lo ogun Amágẹ́dọ́nì láti fi gba ayé lọ́wọ́ àwọn tó fẹ́ bà á jẹ́, kì í ṣe láti fi pa ayé run.​—Ìṣípayá 11:18.

  • Ogun Amágẹ́dọ́nì ló máa fòpin sí gbogbo ogun.​—Sáàmù 46:​8, 9.

Ṣé ó ṣeé ṣe kéèyàn la ogun Amágẹ́dọ́nì já?

Kí lèrò rẹ?

  • Bẹ́ẹ̀ ni

  • Bẹ́ẹ̀ kọ́

  • Kò dá mi lójú

Ohun tí Bíbélì sọ

“Ogunlọ́gọ̀ ńlá” látinú gbogbo orílẹ̀-èdè ló máa la “ìpọ́njú ńlá” já, ìpọ́njú ńlá yìí máa dópin nígbà tí ogun Amágẹ́dọ́nì bá bẹ̀rẹ̀. ​—Ìṣípayá 7:9, 14.

Kí làwọn nǹkan míì tí Bíbélì sọ?

  • Ọlọ́run fẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn la ogun Amágẹ́dọ́nì já. Àwọn ẹni burúkú tí kò yí pa dà nìkan ló máa pa run.​—Ìsíkíẹ́lì 18:32.

  • Bíbélì ṣàlàyé bá a ṣe lè la ogun Amágẹ́dọ́nì já.​—Sefanáyà 2:3.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, ka orí 8 nínú ìwé yìí, Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?, Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é

Ó tún wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́