Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: FEBRUARY 27–APRIL 2, 2017
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
CHILE
Àwọn ará tó wà ní apá gúúsù orílẹ̀-èdè Chile ń ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe kí wọ́n lè wàásù fáwọn èèyàn tó wà káàkiri ìgbèríko láwọn ìgbà tojú ọjọ́ bá dáa. Odò kan tó ń ṣàn gba inú igbó kìjikìji àti àárín àwọn òkè ńláńlá Andes ni wọ́n máa ń tọ̀ débẹ̀.
IYE AKÉDE
76,296
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
64,178
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
174,761
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.