Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
Ọ̀SẸ̀ APRIL 3-9, 2017
3 Ohun Tí Jèhófà Ní Lọ́kàn Máa Ṣẹ!
Ọ̀SẸ̀ APRIL 10-16, 2017
8 Ìràpadà—“Ọrẹ Pípé” Tí Baba Fún Wa
Ó ṣe pàtàkì pé ká lo ìgbàgbọ́ nínú ẹbọ ìràpadà Kristi, ìràpadà yìí náà ló sì máa mú kí ohun tí Jèhófà ní lọ́kàn fáráyé nímùúṣẹ. Nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí, a máa rí ìdí tí ìràpadà fi ṣe pàtàkì, ohun tí ìràpadà náà mú kó ṣeé ṣe àti bá a ṣe lè fi hàn pé a mọyì ìràpadà tó jẹ́ ẹ̀bùn tó tóbi jù lọ tí Baba wa ọ̀run fún wa.
13 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Jèhófà Fi Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Hàn sí Wa Lónírúurú Ọ̀nà
Ọ̀SẸ̀ APRIL 17-23, 2017
18 Jèhófà Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
Ọ̀SẸ̀ APRIL 24-30, 2017
23 Ta Ló Ń Darí Àwa Èèyàn Ọlọ́run Lónìí?
Ọjọ́ pẹ́ tí Jèhófà ti máa ń lo àwọn èèyàn kan láti múpò iwájú. Kí nìdí tá a fi gbà pé Jèhófa ló ń ti àwọn tó ń múpò iwájú lẹ́yìn? Yàtọ̀ síyẹn, báwo la ṣe mọ̀ pé Jèhófà ló ń darí ẹrú olóòótọ́ àti olóye lónìí? Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa jíròrò àwọn ohun mẹ́ta tá a fi ń mọ àwọn aṣojú Jèhófà.