Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
FEBRUARY 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: APRIL 3-30, 2017
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
ETIÓPÍÀ
Arákùnrin kan ń fi Bíbélì wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run fáwọn ọkùnrin méjì tó ń gbé lábúlé. Abúlé tó wà lórí òkè kan lórílẹ̀-èdè Etiópíà ni wọ́n ń gbé. Àwọn ọkùnrin náà da aṣọ tó dà bí aṣọ òfì bora báwọn èèyàn àgbègbè náà ṣe máa ń ṣe
IYE ÈÈYÀN
99,391,000
IYE AKÉDE
10,083
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
25,323
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.