Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MARCH 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MAY 1-28, 2017
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
RÒMÁNÍÀ
Alàgbà yìí àti ìyàwó rẹ̀ rí i pé ẹ̀yìn ìpàdé lọ́jọ́ Sunday ló dáa jù láti bá àwọn èèyàn tó nífẹ̀ẹ́ òtítọ́ nílé ní àríwá orílẹ̀-èdè Ròmáníà. Àwọn aládùúgbò méjì yìí wà lára àwọn tí wọ́n bá sọ̀rọ̀. Wọ́n ń yọ ìdọ̀tí kúrò nínú irun tí wọ́n fá lára àgùntàn.
IYE AKÉDE
40,575
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
25,623
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
78,300
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.