Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MAY 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JULY 3-30, 2017
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ:
ECUADOR
Aṣáájú-ọ̀nà déédéé kan ń wàásù lédè Quichua (Imbabura) fún obìnrin kan tó ń ta aṣọ híhun nínú ọjà nílùú Otavalo ní àríwá orílẹ̀-èdè Ecuador.
IYE AKÉDE
90,110
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
148,637
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
274,593
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.