Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JUNE 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JULY 31–AUGUST 27, 2017
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
GÍRÍÌSÌ
Àwọn ìdílé kan tó ń gbé nítòsí ìlú Áténì ń fi àwọn orin Ìjọba Ọlọ́run dánra wò níbi àpèjẹ kan
IYE AKÉDE
28,816
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
13,237
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
46,822
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.