Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
3 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ṣe Ìfẹ́ Rẹ̀
Ọ̀SẸ̀ NOVEMBER 27, 2017–DECEMBER 3, 2017
7 “Kí A Nífẹ̀ẹ́ . . . ní Ìṣe àti Òtítọ́”
Ìfẹ́ tòótọ́ la fi ń dá àwa Kristẹni tòótọ́ mọ̀. Àpilẹ̀kọ yìí máa sọ àwọn nǹkan mẹ́sàn-án tá a lè ṣe táá fi hàn pé ìfẹ́ wa ò ní àgàbàgebè.—2 Kọ́r. 6:6.
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 4-10, 2017
12 Idà Ni Òtítọ́ Ń Mú Wá, Kì Í Ṣe Àlàáfíà
Ọ̀rọ̀ kòbákùngbé táwọn ẹbí tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń sọ sí wa lè mú kí ayé sú wa. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá a ṣe lè máa sin Jèhófà nìṣó láìka àtakò táwọn mọ̀lẹ́bí wa ń ṣe sí wa.
17 Jósẹ́fù ará Arimatíà Lo Ìgboyà
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 11-17, 2017
21 Bí Àwọn Ìran Tí Sekaráyà Rí Ṣe Kàn Ẹ́
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 18-24, 2017
26 Àwọn Kẹ̀kẹ́ Ẹṣin àti Adé Kan Ń Dáàbò Bò Ẹ́
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé ìran kẹfà, ìkeje àti ìkẹjọ tí Sekaráyà rí. Ìran kẹfà àti keje máa jẹ́ ká mọyì àǹfààní tá a ní láti sin Jèhófà nínú ètò mímọ́ rẹ̀. Ìran kẹjọ máa jẹ́ ká rí bí Jèhófà ṣe ń dáàbò bò wá ká lè máa jọ́sìn rẹ̀.
32 Ǹjẹ́ O Mọ̀?