Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
OCTOBER 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: NOVEMBER 27–DECEMBER 24, 2017
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
NÀÌJÍRÍÀ
Ọ̀kan lára àwọn ibi tá a ti ń wàásù níbi tí èrò pọ̀ sí rèé nílùú Èkó. Ìlú yìí làwọn èèyàn pọ̀ sí jù nílẹ̀ Áfíríkà. Àwọn bíi mẹ́fà lára àwọn tó ń wá síbi ìpàtẹ yìí lóṣooṣù ló máa ń sọ pé ká wá kọ́ àwọn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
IYE AKÉDE
370,336
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
870,185
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
774,874
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.