ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w17 December ojú ìwé 2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
w17 December ojú ìwé 2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí

Ọ̀SẸ̀ JANUARY 29, 2018–FEBRUARY 4, 2018

3“Mo Mọ̀ Pé Yóò Dìde”

Ọ̀SẸ̀ FEBRUARY 5-11, 2018

8 “Mo Ní Ìrètí Sọ́dọ̀ Ọlọ́run”

Àwọn nǹkan tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá wo ló mú kó dá àwa Kristẹni lójú pé àjíǹde máa ṣẹlẹ̀ lóòótọ́? Àwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Ọlọ́run láyé àtijọ́ gbà gbọ́ pé àwọn èèyàn àwọn máa jíǹde, torí náà báwo ni ìdánilójú wọn àtàwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ nígbà yẹn ṣe lè mú kí ìgbàgbọ́ tiwa náà lágbára sí i? Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kó túbọ̀ dá ẹ lójú pé àjíǹde máa wáyé lóòótọ́.

13 Ǹjẹ́ O Rántí?

14 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

16 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ọ̀SẸ̀ FEBRUARY 12-18, 2018

18 Ẹ̀yin Òbí​—Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè “Di Ọlọ́gbọ́n fún Ìgbàlà”

Ọ̀SẸ̀ FEBRUARY 19-25, 2018

23 Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—“Ẹ Máa Ṣiṣẹ́ Ìgbàlà Yín Yọrí”

Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ló ń ṣèrìbọmi lọ́dọọdún. Àwọn tó pọ̀ jù lára wọn ni kò tíì pé ọmọ ogún ọdún, àwọn míì ò sì tíì pé ọdún mẹ́tàlá. Lóòótọ́ ọ̀pọ̀ àǹfààní lẹni tó bá ṣèrìbọmi máa ní nínú ètò Ọlọ́run, àmọ́ àwọn ojúṣe kan wà tó máa já lé e léjìká. Ẹ̀yin òbí, báwo lẹ ṣe lè ran àwọn ọmọ yín lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣèrìbọmi? Ẹ̀yin ọ̀dọ́ tẹ́ ẹ ti ṣèrìbọmi àtẹ̀yin tẹ́ ẹ ṣì ń ronú láti ṣèrìbọmi, báwo lẹ ṣe lè mú kí àjọṣe yín pẹ̀lú Jèhófà túbọ̀ sunwọ̀n sí i?

28 Ìtàn Ìgbésí Ayé​—Mo Fi Àwọn Nǹkan Sílẹ̀ Kí N Lè Tẹ̀ Lé Jésù

32 Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2017

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́